St. Francis Manor & Seeland Park
Skip to Content

Yoruba

St. Francis Manor, Inc. ba ilana ijoba apapo lori ofin eto ara ilu atipe a ko gbodo se ojusaju nipa eya, awo, ilu abinibi,ojo ori, abarapa tabi okunrin ati obinrin. St. Francis Manor, Inc. won ko gbodo yo awon eniyan si ile tabi wuwasi won yato latari eya, awon abinibi, ojo-ori, tabi okunrin abi obinrin.

St. Francis Manor, Inc.

  • Ipese ohun elo ofe ati iranlowo fun awon ti won le so ede lati le ma ba wa soro
    • Akosemose ogbufo odi
    • Kiko oro jade ni ona miran (kiko oro ni titobi, agbohunsile, awon ohun elo igbalode fun ero ayelujara ati awon ona miran.)
  • A npese ogbufo lofe fun awon ti won le so ede oyinbo daada,bii
    • Akosemose ogbufo
    • Kiko oro ni awon ede miran

Ti o ba nfe awon afani wonyi, e kansi Morgan Hawkins or Tiffany Criswell

Ti e ba nigbagbo that St. Francis Manor, Inc.  ti kuna lati seto awon iranlowo wonyi tabi se ojusaju ni awon ona awon ona miran bi eleyameya, omo, ilu-abinibi, ojo-ori, abarapa, tabi okunrin abi obinrin, le fi iwe kotemi-lorun/iwe ifehonu han si: Morgan Hawkins, Compliance Officer or Tiffany Criswell, Quality Coordinator, 2021 4th Avenue Grinnell, IA 50112, 641-236-7592, Fax: 641-269-5497, mhawkins@stfrancismanor.com, tcriswell@stfrancismanor.com. E le fi iwe ifi ehonu han ni ojukoroju tabi nipa fifi ranse ni apo iwe si adiresi wa, fax, tabi ero-ayelujara. Ti eba nilo iranlowo lati ko iwe ifi-ehonu han, Morgan Hawkins, Compliance Officer or Tiffany Criswell, Quality Coordinator wa ni sepe fun yin.

 

YORUBA

E tun le pe kotemilorun latari eto ara-ilu pelu eka eto ilera ati eto Fun ti ile Amerika. U.S Department of Health and Human Services, Office for Civil Rights, Office for Civil Rights Complain Portal, wa ni https://ocrportal.hhs.gov/ocr/portal/lobby.jsf tabi nipa fifi iwe sowo tabi lori ero- ibanisoro ni:

U.S Department of Health and Human Services

200 Independence Avenue, SW

Room 509F, HHH Buiding

Washington, D.C 20201

1800 – 868 -1019 – 800 – 537 – 7697 (TDD)

E le ri foomu fun ehonu ni http:/www.hhs.gov/ocr/office/file/index/html.

 

St. Francis Manor, Inc. tele ilana ofin ijoba apapo lori eto ara ilu atipe won ko gbodo sojusaju lori oro eya awo, ilu-abinibi, ojo-ori, abarapa tabi okunrin ati obinrin.

 

AKIYESI: Ti o ba nso ede Yoruba ofe ni iranlowo lori ede wa fun yin o. E pe ero ibanisoro yi

1-877-696-6775.

Notice of Privacy Practices

|

Unsubscribe from Fundraising Correspondence

|

© 2024 St. Francis Manor & Seeland Park. All rights reserved.